A ki i yin kaabo si orile-ede Russia - The No.1 Infotainment blog

images+%252811%2529

The No.1 Infotainment blog

1532112937

Friday, 25 May 2018

A ki i yin kaabo si orile-ede Russia

Dd96a05V4AAT9IY-696x305

Leyin ise takun-takun, eleyi ti orile-ede Russia ti n gbese lataari sise agbateru ifesewonse idije boolu agbaye to n bo lona, won ti n reti bayii lati se ikinni kaabo awon orile-ede ti yoo kopa ninu idije ohun, ti o fi mo awon ololufe iko agbaboolu kookan jakejado agbaye.
Ewe, iko agbaboolu orile-ede Russia gbe ara tuntun mi yo, leyin ti agbaboolu kookan wo aso igba boolu orile-ede kookan ti yoo maa kopa ninu idije naa, lati ya aworan, ati ni papaajulo lati se ikinni kaabo awon orile-ede ohun.
Asole iko ohun, Igor Akinfeev, ti oun wo aso orile-ede Germany, ti n se iko agbaboolu orile-ede ti o darajulo lagbaye, soro leyin aworan naa pe,A ki iko agbaboolu orile-ede kookan ti yoo maa kopa ninu idije yii,”
eleyi yoo si tun fi han won pe, a ti setan lati gbawon laleejo. Bee si ni, A ti seto sile lopolopo fun gbogbo orile-ede ati awon ololufe iko kookan ti yoo wa si Russia.”
Asiko oorun la wa yii, bee si ni, oju ojo dara pupo. Mo mo daju pe, won yoo gbadun ara won lopolopo.

No comments:

Post a Comment