Adari egbe agbaboolu Super Eagles, ti gbe oruko awon agbaboolu metalelogun (23) to n ko lo si Russia fun idije fun ife eye agbaye – World Cup.
Awon meedogbon (25) lo ti n ko sodi tele, sugbon o ti ja meji sile bayii.
Awon meji naa ni Ola Aina ati Mikel Agu. Sugbon Mikel agba, iyen Mikel Obi n lo si Russia pelu Super Eagles.



No comments:
Post a Comment